Blood Of The Lamb Lyrics by Barry Jhay

Barry Jhay Lyrics

“Blood of the Lamb” by Barry Jhay is a soulful Afro-fusion song of faith, gratitude, and divine hope. Blending Yoruba and English, Barry Jhay reflects on life’s struggles while trusting God’s grace to bring transformation and victory. The track praises God as the “King of Life,” celebrating spiritual strength, perseverance, and divine breakthrough.

Cover art for Barrystar Vol 1 Deluxe Album by Barry Jhay
Barrystar Vol. 1 Deluxe Album Cover Art

Barry Jhay – Blood Of The Lamb Lyrics

Intro
V-V-V-V Sticks

Verse 1
Ijẹtá, ′ṣèni mò kun lẹ, mòfẹ bá Ọlọhun s’ọrọ, miò mọ òhun ti mò fẹ sọ (miò mọ òhun ti mò fẹ sọ)
Bimò ṣè n ri mu, má jẹn mu bọ, Èlèduwá (Èlèduwá)
Ṣá má ṣọmi lọ (Ṣá má ṣọmi lọ)
Baba, one grace yẹn ni, that one transaction
E go change my life for good, oh (e go change my life for good)
Igbágbọ mi sober wọ into gbògàn, òlèku

Pre-Chorus
Ápátá, dákálèlè tilè ò lè wò, Ẹ ṣá l′ágbárá
T’òbá di gbè-gbè gbè
You steady come through for me
Áyè ò fẹ ká r’ẹru, ká sọ, áyé ò fẹ ká palash (fẹ ká r′ẹru, ká sọ, áyé ò fẹ ká palash, palash)
Òhun t′ọmọ èniyàn ò mọ lò pọr ju
B’Ọbá mi bá dè, á dábi wọ l′òmọ ṣèju (‘mọ ṣèju)

Chorus
Ayy, Ọbá iyè, Áṣẹgun iyè, ayy
Iyin át′ògò áti ágbárá, wá dákun gbọ’rọ
Ọbá iyè, Áṣẹgun iyè, ayy-ah
Iyin át′ògò áti ágbárá, wá dákun gbọ’rọ

Verse 2
Ṣèbi iwọ l’ápáṣẹ, t′òn p′áṣẹ
L’òri iṣẹ mi, p′áṣẹ ọtun
N’ilè áyè mi, p′áṣẹ árá ò
Inu ilè mi, p’áṣẹ ò
Ṣèbi mò gb′òju lè, ayy
Ṣèbi mò gb’ọkàn mi lè Ọ
Ki Baba mi f’iyá gbọ òrukọ, áti kọ ọrọ rẹ, titi lái (titi lái)

Pre-Chorus
Ápátá, dákálèlè tilè ò lè wò, Ẹ ṣá l′ágbárá
T′òbá di gbè-gbè gbè, You steady come through for me
Áyè ò fẹ ká r’ẹru, ká sọ, áyé ò fẹ ká palash, yè (fẹ ká r′ẹru, ká sọ, áyé ò fẹ ká palash, palash, yè)
Òhun t’ọmọ èniyàn ò mọ lò pọr ju
B′Ọbá mi bá dè, á dábi wọ l’òmọ ṣèju (′mọ ṣèju)

Chorus
Ayy, Ọbá iyè, Áṣẹgun iyè, ayy
Iyin át’ògò áti ágbárá, wá dákun gbọ’rọ
Ọbá iyè, Áṣẹgun iyè, ayy-ah
Iyin át′ògò áti ágbárá, wá dákun gbọ′rọ

Outro
(Sunshine)

Check Lyrics of latest songs here, and get fresh updates as they drop via X and Facebook

The post Blood Of The Lamb Lyrics by Barry Jhay appeared first on NotjustOk.

Barry Jhay Lyrics “Blood of the Lamb” by Barry Jhay is a soulful Afro-fusion song of faith, gratitude, and divine hope. Blending Yoruba and English, Barry Jhay reflects on life’s struggles while trusting God’s grace to bring transformation and victory. The track praises God as the “King of Life,” celebrating spiritual strength, perseverance, and divine
The post Blood Of The Lamb Lyrics by Barry Jhay appeared first on NotjustOk. Read More

​ 

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *